Orúkọ mi ni Adéoyè👋🏿  Mo fẹ́ jẹ́ ohùn kan fún àwọn ọkùnrin tó fẹ́ ọkùnrin nílẹ̀ Yorùbá, torí pé a gbọ́dọ̀ ní ohùn kan láyé wa.

Ẹ ka ewì mi! Láti ṣe ìyẹn, ẹ tẹ ìkànnì tó wà nísàlẹ̀ ⬇⬇⬇⬇
  • America/Nigeria
  • JoinedSeptember 4, 2021



Stories by Adéoyè
Ìfẹ́ Gátagàta by egbingiga
Ìfẹ́ Gátagàta
Èmi náà... Mo rí ọkùnrin kan tó dára bí egbin... Ẹ kà ìtàn yìí láti mọ̀ gbogbo ohun tí mo máa ṣe nínú ìtàn ké...
ranking #27 in togo See all rankings
Ṣé ìfẹ́ ẹ tó? by egbingiga
Ṣé ìfẹ́ ẹ tó?
Ẹ ka ìtàn yìí láti mọ̀ bí Máyọ̀wá ti ṣe mọ Tańmọla. Ta ni mọ ọlá? Tańmọla yìí jẹ́ ìdí tí Máyọ̀wá ti fi ọkùnri...
ranking #98 in lagos See all rankings